Ninu orukọ naa ti INEC gbe jade, eyi ti akọwe rẹ, Rose Oriaran-Anthony, buwọ lu lọjọ Abamẹta to kọja niluu Abuja, lo ti fidi rẹ mulẹ pe awọn oludije naa...