Wo àwọn orílẹ̀èdè Afrika tí Amẹrika kéde pé wọn kò lẹ́tọ̀ọ́ sí àǹfààní ìgbà díẹ̀ tí wọ́n ní láti gbé ní US mọ́
Ijọba Aarẹ Donald Trump kede pe lẹyin ayẹwo finni-finni ati ijiroro laaarin awon ẹka ijọba, awọn ọmọ orilẹede naa to n gbe l'America ko ni anfaani si eto...