"Ìyá àgbà dá abẹ́ fún ọmọ mi obìnrin láìjẹ́ kí n mọ̀ nípa rẹ̀, torí pé àwọn ọkùnrin máa ń fi obìnrin tí kò bá dá abẹ́ ṣe yẹ̀yẹ́"
Gẹgẹ bi José Carlos Cueto ṣe gbe e jade, nigba ti wọn gbe aba naa sita nile aṣofin Colombia, ọpọ ariyanjiyan lo waye fifi opin si ohun ti wọn lo lewu pupọ...