Asiko ti wọn lawọn ọlọpaa da awakọ naa duro lati yẹ ẹ wo, ṣugbọn ti ko duro, ni wọn sọ pe ọkan lara awọn ọlọpaa naa yinbọn fun un, to si gbabẹ sọda sọrun...