Awọn eeyan lorilẹede Gambia n ṣe iwọde nitori idakureku ina ọba to n ṣẹlẹ lorilẹede naa lati oṣu kẹfa.